Rezas
Bará
Toque Adabí
A - Lẹ́gba kayọ́ kayọ́
R - Lẹ́gba kayọ́ kayọ
A - Lẹ́gba ṣiré Ògún
R - Lẹ́gba ṣiré Ògún
A - Lẹ́gba' ṣiré ṣiré
R - Èṣù lọnà dí burúkú
A - Àbàdò dì burúkú
R - Àbàdọ̀ ọ̀bẹ nfara
A - Èṣù a bánà bánà Èṣù abánàiyé
R - Èṣù abánà bánà Èṣù abánàiyé
A - A máa ṣ'ère ó níba Èṣù abánà dá, a máa ṣ'ère ó níba Èṣù abánà dá
R - A máa ṣ'erè ó níbà Èṣù abánà dá, a máa ṣ'erè ó níbà Èṣù abánà dá
A - Èṣù adé mi ṣe ṣe mi re
R - Bàrà adé mi ṣe ṣe mi re
A - Èṣù adé mi ṣe ṣe mi Bàrà
R - Bàrà adé mi ṣe ṣe mi re
A - Èṣù jálànà fun wa
R - Èṣù jálànà fun Malè
A - Èṣù ja Lànà di dè
R - Èṣù b'erin, Èṣù mẹ́rin lànà
A - Èṣù Olóde!
R - Èṣù, Èṣù Obara lọnà
A - Mojúbà Èṣù!
R - Bàrà !
A - Lóde Èṣù!
R - Bàrà!
A - Lọnà Èṣù !
R - Bàrà!
A - Aiyéraiyé, o le Bàrà o! Aiyéraiyé, o le Bàrà A má ṣe lo ogun o! A
má ṣe lo ogun já! aiyéraiyé, o le Bàrà o!
R - Aiyéraiyé, o le Bàrà o! Aiyéraiyé, o le Bàrà A má ṣe lo ogun o! A
má ṣe lo ogun jà! aiyéraiyé, o le Bàrà o!
A - Èṣù Bàrà o ẹlẹ́fa epo
R - Aiyéraiyé, o le Bàrà!
A - Ó yá, ó yá
R - Ó yá o eléfa!
A - Èṣù Bàrà èle o!, Èṣù Bàrà èle o!, mo dì Bàrà ó eléfa epo
R - Èle Bàrà èle ó! èle Bàrà èle ó! mo dì Bàrà ó ẹlẹ́fa epo!
A - Ä là lùpa o!
R - Á là lùpa ṣé máa!
A - Ä là lùpa o!
R - Á iy o que bara!
A - Ä là lùpa o!
R - Á iy o bara bara!
A - Èṣù dé yí, mo jí Bàrà Èṣù á jó, mo júbà yìn
R - Èṣù dé yi, mo dì Bàrà Èṣù á jó, mo júbà yìn
A - Bàrà gbó alároye a Èṣù lọnà, Bàrà gbó alároye a Èṣù lonà, ọmọde kó
ni kóo ṣí Bàrà ogun tàlà bò, Bàrà ó eléfa lọnà
R - Bàrà gbó alaroye a Èṣù lonà, Bàrà gbó alaroye a Èṣù lọnà, ọmọde kó
ni kóo sí Bàrà ogun tàlà bò, Bàrà ó eléfa lọnà
A - Èṣù Bàrà wẹ̀ bàbá oníre
R - Á lù fá Bàrà-Èṣù, ké ké lù fá
A - Bàrà rá mújẹ kún lò ọ̀dà, Bàrà rá mújẹ kún lò ọ̀dà, bàbá ru ekọ
Bàrà ru dẹ o Bàrà rá múje kún lò ọ̀dà, Bàrà mọ́ ré ru
R - Je'kọ l'òdà
A - Bàrà mọ́ ré ru
R - Jẹ'kọ lò dà
A - Bàbá ' iyan' lẹ
R - Bàbá ' iyan' lẹ
Aguere
A - Èṣù lànà fọ̀ mi o, Bàrà lànà fun malẹ̀ o!
R - Èṣù lànà fọ mi o, Èṣù lànà fun malẹ̀!
Batá
A - Bará àjẹlù, Bará àjelù àṣẹ bọ, Bará àjẹlù àṣẹ bọ̀, o yá nílẹ o!
R - Bará àjẹlù, Bará àjelù àṣẹ bọ, Bará àjẹlù àṣẹ bọ̀, o yá nílẹ o!
A - Èṣù Bàrà lọ bẹbẹ tí riri lnà, Bàrà lọ bebe tí riri lọnà, Bàrà Èṣù
tí riri lọnà, Èṣù tirirí
R - Bàrà Èṣù tí riri lọnà, Èṣù tí riri lọnà, Bàrà' kè Bàrà Èṣù Bàrà
Èṣù tí riri lọnà
Aguere
A - Èṣù dá lànà ṣ'ebí a ṣẹ bọ
R - Èṣù dá lànà sí ebọ
Djeje
A - O lè Bàrà yà b'odù màá sànà bọ̀ rẹ̀ Elẹgba
R - O lè Bàrà yà b'odù màá sànà bọ̀ rẹ̀ Elẹgba
A - O lè Bàrà yà b'odù, á sá k'èrè k'ewé
R - O lè Bàrà yà b'odù, á sá k'èrè k'ewé
A - Yà b'odù máa d'okerè k'èrè k'èrè d'ok'ọrọ̀ k'ọrọ̀ k'orọ̀, dó k'èrè
k'èrè k'èrè yà b'odù máa Elẹ́gbà
R - Yà b'odù máa d'okerè k'èrè k'èrè d'ok'ọrọ̀ k'ọrọ̀ k'ọrọ̀, dó k'èrè
k'èrè k'èrè yà b'odù máa Elẹ́gbà
A - Bàrà mọ́tótó mọ́tótó mo dúpe o
R - Bàrà' mí àjó k'èrè ké, á mo dúpe o
A - Ògún lé bá Ògún ṣe rere
R - Ògún!
A - Ògún dé yi aiyé aiyé
R - Ògún dé yi ọnà iṣọ́
A - Ògún òní rà aláṣe' bọ
R - Ògún dé yi onà iṣọ́
A - Ògún a bè ọ Ògún oníṣẹ́ o Ògún oníṣẹ́ o Ògún oníṣẹ́ Ògún
R - Ògún a bè ọ Ògún a oníṣẹ́ o Ògún a onísẹ́ o Ògún a oníṣẹ Ògún
A - Elẹ́gbà yà b'odù!
R - Á b'àdó yó bẹ̀ f'ara
A - Tamaki ẹlìjó tamaki ẹ kà pẹ'jó
R - Tamaki á kọ́'ṣù Lẹ́gba, tamaki ẹlìjó
A - O Lẹ́gba o !
R - Àkàrà jà!
A - Ga máa ṣekọ
R - Àkàrà jà!
A - ṣàngó dé là, wá bájà sí Ògún o, wá bájà sí yà ọ̀le
R - ṣàngó dé là, wá bájà sí Ògún o, wá bájà sí yà ọ̀le
ÒGÚN
Agere t ọdẹ
A - Ògún tàlà b'odù Ògún tàlà moore
R - Ògún tàlà b'odù Ògún tàlà moore
A - Ògún Ògún fẹ́ni fẹ̀ oní b'ọ̀la Ògún
R - Ògún Ògún fẹ́ni fẹ̀ oní b'ọ̀la Ògún
A - Ògún Loko loko mi !
R - Òrò bẹ f'ara
A - Ògún a ríọ , a ríọ l'okerè!
R - Ògún a ríọ , a ríọ l'okerè!
A - A má joko ní Ògún o
R - Erúnmalẹ̀, a má joko ní Ògún o, Erúnmalẹ̀!
A - O Ògún orun odò wá má kọ́ni èle, abọgún wáọnà ijó wá jà bá mi o!
R - O Ògún orun odò wá má kọ́ni èle, abọgún wá ọnà ijó wá jà bá mi o!
A - Ara Ògún orun odò!
R - Aríọ, ara Ògún orun adò, aríọ!
A - ẹrun dé oko èro èlò aga' re o!
R - ẹrun dé oko èro èlò wà ga' re o!
A - Ògún s'irin bọ̀ pa k'ọta kó márájò, Ògún s'irin bọ̀ pa k'ọta kó
márájò, Ògún s'irin bò òrìsà Orí ọkọ
R - Ògún s'irin bọ̀ pa k'ọta kó márájò, Ògún s'irin bọ̀ pa k'ọta kó
márájò, Ògún s'irin bò òrìsà Orí ọkọ
A - Ògún, Ògún a foríba
R - Á mu ro á mu fẹ́ rere
A - Ògún, Ògún wá fá bá mi
R - Á mu ro á mu fẹ́ rere
A - Ògún Oníìre máa jà alágbedè
R - Ògún omníra oná iṣó kèrekè
A - Ògún Oníìre máa jà alakoró!
R - Ògún omníra ọná iṣó kèrekè
A - ṣó, ṣó ṣó !
R - Ògún omníra ọná iṣó kèrekè
A - Ògún adé ìbà!
R - Adé pa, Ògún fá rere
A - Àdá ìbà, àdá ìbà!
R - Adé pa, Ògún fá rere
A - Ògún tàlà bá ìṣòro a bẹ̀ ṣe Ògún!
R - Ògún tàlà bá ìṣòro a bẹ̀ ṣe o!
Ajagun
A - Ògún tàlà jó
R - Ògún lài, Ògún lài, Ògún
A - Ògún òní rà wá ketù ebọ
R - Ògún òní rà wá s'ékú ebọ
A - ọ̀rọ̀ mi o tàlà dé erúnmalẹ̀
R - ọ̀rọ̀ mi o tàlà dé erúnmalẹ̀
A - Ògún tàlà dé tàlà Ògún
R - ọ̀rọ mi o tàlà dé erúnmalẹ̀
A - ọ̀ní rò ọpẹ́ òní rò ọpẹ́ , Ògún á níre òní rà wá tẹ́ wá Ògún á
níre òní rà wá tẹ́ wá Ògún máa ilé
R - ọ̀ní rò ọpẹ́ òní rò ọpẹ́ , Ògún á níre òní rà wá tẹ́ wá Ògún á
níre òní rà wá tẹ́ wá Ògún á níre
A - ẹ Ògún bẹrẹ mi
R - Ara Ògún á níre
A - ẹ Ògún bẹrẹ a máa
R - Ara Ògún á níre
A - Ara nú aré o, ara nú aré o wá má fẹ̀ kẹlẹ̀
R - Ara nú aré o Ògún dé!
A - E wá má fẹ̀ kẹlẹ̀
R - Ara nú aré o Ògún dé!
A - Ògún adémi o!
R - ẹlẹ́fa tàlà adémi o!
A - ẹ ẹ ademi o!
R - ẹlẹ́fa tàlà adémi o!
Aguere
A - Ògún Oníìre, Ògún lòró, Ògún dá lò jà èpé Ògún Oníìre, Ògún lóró,
Ògún dá lò jà erúnmalè
R - Ògún Oníìre, Ògún lòró, Ògún dá lò jà èpé Ògún Oníìre, Ògún lóró,
Ògún dá lò jà erúnmalè
A - Ògún dé aníre, íre íre Ògún lò akara de o aníre íre íre Ògún lò
R - Ògún dé aníre, íre íre Ògún lò akara de o aníre íre íre Ògún lò
A - A bẹ̀ là mú jà, a bẹ̀ là mú'rè
R - A bẹ̀ là mú jà òkerè o!
A - Òkerè o!
R - Aki ṣòro
A - Fara riri má fara mi ya, má fara mi ya, má fara Ògún
R - Kóòro rò rò rò má fara mi ya, má fara mi ya, má fara Ògún
A - Ògún tàlà jó
R - Ògún lài, Ògún lài, Ògún
Batá
A - Ògún fara fara fara Ògún fara márájò
R - Ògún fara fara fara Ògún fara márájò
A - Oníìra ọpẹ, Oníìra ọpẹ, Ògún á níre Oníìra wá tẹ́ wá Ògún á níre
Oníìra wá tẹ́ wá Ògún á níre
R - Oníìra ọpẹ, Oníìra ọpẹ, Ògún á níre Oníìra wá tẹ́ wá Ògún á níre
Oníìra wá tẹ́ wá Ògún á níre
A - Ka' lú' lú
R - O yàn, a bẹ̀ là mú jà
A - Ògún bẹ́ wò a yìn pàra Ògún àjọ Ògún bé wò a yìn pàra Ògún àjo
Ògún bá ga
R - Àdé wa rà wàrawàra àdé wá ra
A - Kò yà kò yà kò yà Ògún dé yi á ko yà kò yà
R - Kò yà kò yà kò yà Ògún dé yi á ko yà kò yà
A - Dé yi, dé yi Ògun á bá ga Ògún dé yi
R - Dé yi, dé yi Ògun á bá ga Ògún dé yi
A - Ta ta ta sá yãnyãn Ògún tàlà jó sá yãnyãn
R - Ta ta ta sá yãnyãn Ògún tàlà jó sá yãnyãn
A - Ògún méje méje
R - Ara Ògún méje n' Ire o
A - Tòní molé k'ewé tòní molé k'ewé tòní mọlé k'ewé olówurọ
R - Fara Ògún mọ ìtan
A - Ògún pa rà yára Ògún lọ Ògún òní rà ẹ ká s'àjọ
R - Pa rà yára Ògún lọ Ògún òní rà ẹ ká s'àjo
Djéjé
A - Ògún fara fara fara Ògún fara márájò
R - Ògún fara fara fara Ògún fara márájò
A - Ògún dé yi aiyé aiyé
R - Ògún dé yi ọnà iṣọ́
A - Ògún òní rà aláṣe' bọ
R - Ògún dé yi onà iṣọ́
A - Ògún a bè ọ Ògún oníṣẹ́ o Ògún oníṣẹ́ o Ògún oníṣẹ́ Ògún
R - Ògún a bè ọ Ògún a oníṣẹ́ o Ògún a onísẹ́ o Ògún a oníṣẹ Ògún
A - Ògún máa ká máa ká kabiyesi l'abẹ̀ o
R - Ògún máa ká máa ká kabiyesi l'abẹ̀ o
A - Ògún èlè fa lái-lái Ògún eléfa lái là
R - ẹ dé lái lái lái Ògún eléfa lái là
A - ẹ dé lái lái lái ṣàngó ẹ dé wẹ̀
R - ẹ dé lái lái lái ṣàngó ẹ dé wẹ̀ dé lái là
A - Ògún òní rà Ògún lò rọ̀
R - Wá máà kẹ ̀rè kẹ̀rẹKẹ̀rẹ Ògún lò rọ̀
OYÁ
Adabí
A - Ado ado a sè máa ado sè dé l'ọya
R - Ado ado a sè máa ado sè dé l'ọya
A - A pàra jẹun ado ké
R - ọya!
A - ọya sè jẹun ado ké
R - ọya!
A - ọya pa ọya pa ọya pa yọ ké
R - A pàra jeun asèje ọya pa yọ ké
A - Á má yà, má yà, má yà, já'yọ̀ já'yọ̀ á má yà mu sè ké bá já'yọ̀
já'yọ̀
R - Á má yà, má yà, má yà, já'yọ̀ já'yọ̀ á má yà mu sè ké bá já'yọ̀
já'yọ̀
A - ọbẹ̀ rẹ sè máa niṣẹ́ o
R - ọya d'oko ọbẹ sè o
A - ọbẹ̀ rẹ sè ọya ní jà o
R - ọya d'ọkọ ọbẹ̀ sè o
A - ọya níre ọbẹ rẹ sè ká ri dé Ògún
R - ọya níre ọbẹ rẹ sè ká ri dé Ògún
A - ọbẹ rẹ sè ká ri dé Ògún
R - ọya níre w'adé wá
A - ọya má wé ru té
R - ọ̀bẹ sè ọrọ̀ koro
A - Kan' lù'lù dé
R - Àwo ro omi ni là ọ̀rọ
A - Olomi láyọ̀, olomi lọ yà wá màá kérè kérè kérè wẹ́lẹ́ wé é wá yọ
R - Olomi láyọ̀, olomi lọ yà wá màá kérè kérè kérè wẹ́lẹ́ wé é wá yọ
A - A ri Yànsán éèdì lọ yà, a ri Yànsán éèdì lọ yà, a ri Yànsán éèdì
lọ yà, erúnmalè ẹ mọ̀dí bádù
R - A ri Yànsán éèdì lọ yà, a ri Yànsán éèdì lọ yà, a ri Yànsán éèdì
lọ yà, erúnmalè ẹ mọ̀dí bádù
A - ọya' ka'lù'lú, Yànsán s'ẹni ebọ
R ọya' ka'lù'lú, ọya s'ẹni ebọ
A - Wá màá'nà màá nà dé l'oke
R - A ri Yànsán éèdì lọ yà
A - Ògún mélò mélò dé'wu ?
R - A ri Yànsán éèdì lọ yà
A - Òní rà ẹlù ọta wa o!
R - A ri o òní rà ọ̀be ṣé o!
A - ẹlù ọta wa o!
R - A ri o òní rà ọ̀bẹ ṣé o!
A - ẹlù ọta mi o!
R - A ri o òní rà ọ̀bẹ ṣé o!
Agere
A - ọya má tẹ́ o ariwo, àkàrà, oyin, já kó lo
R - ọya má tẹ́ o ariwo, àkàrà, oyin, já kó lo
A - A ri Yànsán éèdì lọ yà, pàra óògún dé l'ọya
R - A ri Yànsán éèdì lọ yà, pàra óògún dé lọ yà
A - ẹ̀bi yà odo wa ọya dé ẹ̀bi yà odo wa ọya dé, Yànsán-ọya ẹ pẹ́ èbi
yà odo wa ọya dé
R - ẹ̀bi yà odo wa ọya dé ẹ̀b yà odo wa ọya dé, Yànsán-ọya ẹ pẹ́ èbi
yà odo wa ọya dé
A - ẹ̀bi a odo a ọya dé ẹ̀bi a odo a ọya dé, èlè wá rà èpé ẹ̀bii yà
odo wa ọya dé
R - ẹ̀bi a odo a ọya dé ẹ̀bi a odo a ọya dé, èlè wá rà èpé ẹ̀bi yà odo
wa ọya dé
A - Àṣàṣé wà àdé!
R - Àdé wá aiyé
A - A! káà tẹ́ra wẹ̀
R - Àdé wá aiyé
A - Abádọ̀ ọ̀rọ̀ kó Yànsán a dupé ọ̀rọ̀ kó màá re jó
R - Abádọ̀ ọ̀rọ̀ kó Yànsán a dupé ọ̀rọ̀ kó màá re jó
A - Ògún là ká padọ̀ Yànsán!
R - ọ̀rọ̀ kó mi yányán ọya
A - Yànsán lè pa fúù he
R - ẹ pa!
A - Ògún ké lè p'ara
R - ẹ pa!
A - Yànsán kun Ògún
R - ẹ pa!
A - Ògún kun Yànsán
R - ẹ pa!
A - Ògún lépa' kú yé
R - ẹ pa!
Batá
A - Wẹ́lẹ́ wẹ́lẹ́ b'èyí kò
R - ọya wẹ́lẹ́ wẹ́lẹ́ b'èyí kò
A - Ògún ọrẹ́ pé tẹ
R - ọrẹ pé!
A - ṣọ rọ̀ rọ̀ oke mi laiyà yá, omi ni laba lò kí l'ọya
R - ṣọ rọ̀ rọ̀ oke mi laiyà yá, omi ni laba lò kí l'ọya
A - ọya k' àrá boro kọ
R - ọya d'oko ọya níṣé
A - ẹkọ́ dọ́ eko ó ní' kọ́ ró
R - ọya d'oko ọya níṣé
A - ọya e e e e !
R - ọya e e e e !
A - ọya e yé aiyé !
R - ọya e yé aiyé !
A - F'ara Ògún fara Ògún fara bá ìṣẹ́ rò ẹ̀rọ̀
R - F'ara Ògún fara Ògún fara bá ìṣẹ́ rò ẹ̀rọ̀
A - Ògún Aláiyé!
R - Fara Ògún fara
A - Fara Ògún lọ́ ọya
R - ọya' níre
A - ọya másé mi lọ yá ọya máṣé mi lọ yá l'òrun bẹ̀ wò
R - ọya másé mi lọ yá ọya máṣé mi lọ yá l'òrun bẹ̀ wò
A - Àkàrà lè yí lè yí abo f'ohùn òrìṣà l'ọ̀run dé o
R - Àkàrà lè yí lè yí abo f'ohùn òrìṣà l'ọ̀run dé o
A - Á d'okun le mọ̀ yio á d'okunlá se jó àṣẹ nsùn là ṣe jó ọya màá tẹ́
wò
R - Á d'okun le mọ̀ yio á d'okunlá se jó àṣẹ nsùn là ṣe jó ọya màá tẹ́
wò
A - ọya dé' lú yá, ọya dé'lú yá l'ọ̀run bẹ̀ wò ọya dé' lú yá
R - ọya dé' lú yá, ọya dé'lú yá ọya dé' lú yá
A - Lòrun bè wò
R - ọya dé' lú yá
A - ẹ lò ire ẹ̀pa rà màá o, e lo ire ẹ̀pa rà tó
R - ẹ lò ire ẹ̀pa rà màá o, e lo ire ẹ̀pa rà tó
A - ẹrun dé ọya d'oko ero
R - ẹrun dé ọya d'oko èrọ̀
A - ọya d'oko
R - ẹ̀rọ ẹ̀rọ̀ !
Djéjé
A - Ó bí là yà ó bí là yà!
R - ọya má ké kekẹrẹ
A - ṣàngó l'ọya !
R - Òkerè kéré wé ẹsẹ̀
A - ọya ọya ọya ní' gódò, ọya ní' gódò sá padà ní gódò
R - ọya ọya ọya ní' gódò, ọya ní' gódò sá padà ní gódò
A - Kò mò l'ọkọ mò l'ọdẹ? kò mò l'ọkọ mò l'ọya? Kò mò l'ọkọ mò l'ọdẹ
kò mò l'ọkọ mò l'ọya? ọya bádéṣé!
R - Sálọ mbẹ ! Sálọ mbẹ sé wá!
A - Àjà jagun aṣeni l'ọya ṣeni l'ọya
R - Àjà jagun aṣeni l'ọya ṣeni l'ọya
A - ẹ ire ọya bọ́ bọ̀
R - ọya yé a bẹ̀ fẹra
A - ọya bọ́ bọọ̀
R - ọya yé, a bẹ̀ fẹ́ra
A - Oníṣàngó bà yìn yá ọya d'oko Àgànjú kabiyesi'lé oníṣàngó bà yìn
R - Oníṣàngó bà yìn yá ọya d'oko Àgànjú kabiyesi'lé oníṣàngó bà yìn
ṣàngó
Jeje (huntó)
A - Alárun dé ṣàngó ká mù'ka Bàbá o bá rò' fin là
R - Alárun dé ṣàngó ká mù'ka Bàbá o bá rò' fin là
A - Alárun dé!
R - ṣàngó ká mù'ka
A - Bàbá rò' fin là
R - ṣàngó ká mù'ka
A - Wólè wólẹ̀ wólẹ̀ kábíyèsílẹ̀ àdé!
R - Wólè wólẹ̀ wólèkábíyèsílẹ̀ àdé!
A - L'òkè !
R - Sá bu èlò
Tonigbobe ilú
A - Olúwa gun bàábo igbó ẹlẹfà l'òrìṣà, Olúwa gun bàábo igbó ẹlẹfà nú
ebọ
R - Olú wò gùn má bó igbo èle fà l'òrìṣà, Olú wò gùn má bọ́ igbo èle
fà l'òrìṣà
A - Olúghohún má bọ́ igbo èle fà l'òrìṣà, olú wò gùn má bọ́ igbo èle
fà l'òrìṣà
R - Olú wò gùn má bọ́ igbo èle fà l'òrìṣà, Olú wò gùn má bọ́ igbo èle
fà l'òrìṣà
A - Aganjú ẹ̀kọ́ mi'nà' wè jéjé ori jẹ́jẹ́ Aganjú ẹ̀kọ mi'nà' wè
jẹ́jẹ́ ori ṣàngó
R - Aganjú ẹ̀kọ́ mi'nà' wè jéjé ori jẹ́jẹ́ Aganjú ẹ̀kọ mi'nà' wè
jẹ́jẹ́ ori ṣàngó
A - Òdodo sí èmi r'emi Aganjú màá ní ṣé ọlà, òdodo mọ̀ èrè mi ṣàngó,
Àgànjú màá ní ṣé ọlà
R - Òdodo sí èmi r'emi Aganjú màá ní ṣé ọlà, òdodo mọ̀ èrè mi ṣàngó,
Àgànjú màá ní ṣé ọlà
A - Àgúnta o!
R - Màá níṣé ọlà !
A - Ga màá Aládé o!
R - Lókun kerèrè!
A - Ìbọ̀ moore!
R - Kerèkè ìbọ̀ moore kerèkè!
A - ṣorò ṣorò o ní'godo
R - ṣorò ṣorò o ní' ṣàngó
A - Akun bẹ̀' rí
R - Àrá akun bẹ̀' rí àrá
A - Àgànjú ẹkùn èrè pe
R - Àgànjú ẹkùn s'ara yà
A - S'ara yà ká fá'mọdẹ s'ara yà ká fá'mọde wò!
R - O yà' ba dilé s'ara yà ká fá'mọde!
A - Onípè ni ṣàngó
R - Abá' dó onípè o yá bá' dó
A - Ègé bọ̀'re wa Agodó sá là sá là sá o!
R - Ègé bọ̀'re wa Agodó sá là sá là sá o!
A - Kan'lù'lù, kan'lù' lù dé
R - ọnà rèé o kan'lù'lù dé
Agere
A - Alubàtá o! kábíyèsílẹ̀ ndé o!
R - Alubàtá o! kábíyèsílẹ̀ ndé o!
A - Agodó màá iyọ, agodó màá iyọ àtéwó ya Àgànjú màá yọ àtéwó ya òdodo
màá iyọ
R - Agodó màá iyọ, agodó màá iyọ àtéwó ya Àgànjú màá yọ àtéwó ya òdodo
màá iyọ
A - Káwọ́ kábíyèsíẹ ọmọ ṣèré ọmọ júbà
R - Káw kábíyèsílẹ̀ ọmọ ṣèré ọmọ júbà
A - Nà àgò'rò ai àjà orò
R - Àgò yé yé!
A - ọmọ júbà!
R - Lái lái mojúbà aiyé ọmọ júbà, lái lái ọmọ júbà aiyé
A - Káwọ!
R - kábíyèsílẹ!
Casun Toque Alujá
A - ẹlìjó' gòdó a k'àrá wó, a ní ṣé wó, a ní ṣé wó
R - ẹlìjó' gòdó a k'àrá wó, a ní ṣé wó, a ní ṣé wó
A - Adé wó wó!
R - A ní ṣé wó, a ní sé wó
A - A ní ṣé wó ta pariwó!
R - A ní ṣé wó abà orò!
ALUJÀ
O Aká ká tigbó lo finná ni ṣàngó, àká ká bàbá lo finná na' re wa
R - A yé ààyè ààyè, a yé ààyè ààyè!
A - Ka' lú' lú dé, la' lú' lú dé, è dè' káàbò kábíyèsílẹ̀ ayé, è dé
káàbò kábíyèsílẹ̀ ayé
R - Ka' lú' lú dé, la' lú' lú dé, è dè' káàbò kábíyèsílẹ̀ ayé, è dé
káàbò kábíyèsílẹ̀ ayé
O Olokun dé o!
R - Ara dé kún dé kún dé kaá!
A - Ara kún dé!
R - Ara dé kún dé kún dé kaá!
Djéjé Sango Sobo (Vodun)
A - Sobo ibọ̀ yé!
R - Aiọkọ̀ lái-lái ṣànbo ilúwẹ aiọkọ̀ lái-lái?
A - Sobo ndé!
R - Akágun alárun dé, ayé, aiyé, akágun alárun dé
A - Olókun dé!
R - Akágun alárun dé, ayé, aiyé, akágun alárun dé
A - Sobo báyi alárun dé, Sobo báyi alárun dé, bá yi alárun dé, Sobo bá
yi
alarun dé o!
R - Sobo báyi alárun dé, Sobo báyi alárun dé, bá yi alárun dé, Sobo bá
yi
alarun dé o!
Odé e Otim
Adabí
A - ọṣan pá èrè pẹ́ ọmọ olurọ̀ èrè pẹ o
R - ọṣan pá èrè pẹ́ ọmọ olurọ̀ èrè pẹ
A - Mí n'ẹrọ̀ mí n'ẹrọ ọdẹ mí n'ẹrọ mí n'ẹrọ ọdẹ!
R - ọṣan pá, mí n'ẹrọ mí n'ẹrọ ọdẹ
A - ọdẹ o m'ọ́ta!
R - ọtìn bò rò ọdẹ
A - ọdẹ m'ọ́ta, m'ọ́ta ọtìn bọ̀ rọ̀
R - ọdẹ m'ọ́ta, ọtìn bọ̀ rọ
A - ọdẹ àjà kùnà pani rọ́, àjà kùnà pani rọ́ àjà kùnà èdé m'ọdẹ m'ọtìn
á ká rere o, àjà kùnà pani rọ́!
R - Àjà kùnà pani rọ́, àjà kùnà pani rọ́ àjà kùnà, èdé m'ọdẹ m'ọtìn á
ká rere o, àjà kùnà pani rọ́!
A - Èdé m'ọdẹ m'ọtìn á ká rere o!
R - Àjà kùnà pani ró
A - ọdẹ pa mi láro
R - ọdẹ pa mi láro
A - ọdẹ pa mi láro sà f'ọmọde
R - Pa mi láro sà f'ọmọde
A - Eh! a ba ọdẹ, a ba ọdẹ !
R - Ara ṣọ́ ṣọ́ wá ọdẹ
A - ṣé ká relé ṣé ká relé wa?
R - Ayanṣé' yanṣé ká relé!
A - Diga là ire, là ire pẹ, diga là ire, là ire pẹ, diga là
R - Aaa yé aaa yé! Diga là ire là ire pẹ, diga là
A - Esun là esun lò aberikunlo a wè àwon
R - Esun là esun lò aberikunlo a wè àwon
A - ọtìn yé aayé!
R - Yé aayé!
A - ọtìn a koro!
R - A koro !
A - ọtìn abeṣù!
R - A koro !
A - ọdẹ ọmọ ṣ'itẹ a dìde o!
R - ọdẹ ọmọ ṣ'itẹ a dìde o!
A - Bẹrẹ bẹni ṣó dé, bẹrẹ bẹni ṣó dé, àká ká o kún, o kún f'erè mi,
bẹrẹ bẹni ṣó dé
R - Bẹrẹ bẹni ṣó dé, bẹrẹ bẹni ṣó dé, àká ká o kún, o kún f'erè mi,
bẹrẹ bẹni ṣó dé
A - Èrè akókè r'okè!
R - Òkè akokè r'okè òkè
A - ọdẹ ṣe màá laiya ṣe'rúnmalè, ọdẹ ṣe màá laiya ṣe'rúnmalẹ̀
R - Òrorò ró kún dé, ọdẹ ṣe màá laiya ṣe'rúnmalẹ̀
A - Olóògun bẹ́ẹ̀ wò
R - Olóògun bẹ́ẹ̀ wò
A - ẹ ẹ jí ọ̀wẹ̀
R - Á jíọ̀wẹ̀
A - Á jí ọ̀wẹ̀ lọ
R - A jí ọ̀wẹ̀ lọ ogun
A - ọdẹ pẹre mi ọdẹ pẹre mi
R - Oogun f'èrè mi
A - Èrè bere ké tì
R - A ìró maa yọ́ Erúnmalẹ̀ a ríọ
A - ọdẹ ire'yin ọdẹ mi're wá yára wò yára òkè olóbe ìṣé kári rè wò
R - ọdẹ ire'yin ọdẹ mi're wá yára wò yára òkè olóbe ìṣé kári rè wò
A - Bá mọ́ rà bá mo dé bá mọ́ m'ara k'àjà ọdẹ
R - Bá mọ̀'ra bá' mọdẹ bá mọ́ m'ara k'àjà ọdẹ
A - Kò ní' mọde kò ní jà bi
R - ọtìn
A - E ní' pópó okun ẹ lè sin ẹ lè sí okuta
R - E ní' pópó okun ẹ lè sin ẹ lè sí okuta
Djéjé odé e otin
A - ọdẹ ' tìn bọ̀ rọ̀ ró' tìn bọ̀ rọ̀ ọdẹ m'ọ́ta' tìn bọ̀ rọ̀
R - ọdẹ ' tìn bọ̀ rọ̀ ró' tìn bọ̀ rọ̀ ọdẹ m'ọ́ta' tìn bọ̀ rọ̀
A - O yà bere ké tẹ́ o yà bere ke tẹ́wá rà
R - O yà gbogbo, o yà bere ké té o yà bere ke té wá rà, o yà gbogbo
A - ọdẹ èrè mi
R - ọdẹ ẹran wò!
A - Pere mi pẹrẹ mi
R - ọdẹ ẹran wò!
OBA
Ilú
A - Odò f'ìyá odò f'ìyá
R - Oba s'ire odò f'ìyá
A - Onà goro onà goro bàbà ìrá wò
R - Onà goro onà goro bàbà ìrá wò
A - Èrùn' sele èrùn' sele bàbà ìrá wò
R - Èrùn' sele èrùn' sele bàbà ìrá wò
A - Èrùn rè, o lè gbowó nlè ò kò k'iná' ba
R - Èrùn rè, o lè gbowó nlèrò kò k'iná' ba
A - Là' bata
R - Aláabata
A - Là' bata
R - Kún se rèrè
A - Ak'òjò padò n'iro, E iyo ak'òjò padò n'iro, E iyo
R - Alàgba e ak'òjò padò n'iro, E iyo
A - Ìyá ìyá o dé oko fi lànà
R - Ìyá ìyá o dé oko fi lànà
A - Okùnrin jà le un
R - Ìyá ìyá o dé
A - Sé'lè kún sé'lè kún
R - Sé'lè kún sé'lè kún' sé
A - Emi emí àjó kún'fé lè, emi emí àjó kún'fé lè, abo bò 'fé lomi, emi
emí àjó kún'fé lè
R - Emi emí àjó kún'fé lè, emi emí àjó kún'fé lè, abo bò'fé lomi, emi
emí àjó kún'fé lè
A - Odò oko fere mí
R - Odò oko fè Oba
A - A bájà n'ire a bájà n'ire a bájè n'ire ofìn Odò
R - A bájà n'ire
A - Ofìn Odò
R - A bájà n'ire
A - Oba elékù àjà osi, Oba elékù àjà osi, Olóba só gbó bá, Oba elékù
àjà osi
R - Oba elékù àjà osi, Oba elékù àjà osi, Olóba só gbó bá, Oba elékù
àjà osi
Batá
A - S'apá d'orò
R - Kó mi yányán
A - S'apá d'orò
R - Kó mi yányán
A - S'apá d'orò
R - Kó mi yányán s'apá d'orò kó mi yányán
A - Oba Oba omi
R - O yá sùngbèmi
A - Oba Oba omi
R - O yá sùngbèmi
A - Oba Oba omi
R - O yá sùngbèmi Oba Oba omi o yá sùngbèmi
A - Oko kún dé!
R - Bàbà n'ire
Djéjé
A - Oba oníṣàngó ṣàngó dé Oba Oba d'aiyé
R - Oba oníṣàngó ṣàngó dé Oba Oba d'aiyé
A - Bò bo ganjin omnira f'ara rà màá ganjin omnira
R - Bò bo ganjin omnira f'ara rà màá ganjin omnira
A - ọdẹ yi Oba ta'fa mágùn mágùn
R - ọdẹ yi Oba ta'fa mágùn mágùn
ÒSANYÌN
Korin Ewé
A - Nú a jà kún a bá omi
R - Nú àjé wá, nú aseni
A - Á sun e l'iná Bàbá omo sun e l'iná Bàbá
R - Á sun e l'iná Bàbá omo sun e l'iná Bàbá
A - Òsanyìn dá imó re
R - A ri o màá yo erúnmalè a ri o
A - A tinrin tin tin
R - A ri o màá yò erúnmalè a ri o
A - Òsanyìn bá ìsòro èrò màá yò, Òsanyìn bá ìsòro èrò màá yò
R - Òsanyìn bá ìsòro èrò màá yò, Òsanyìn bá ìsòro èrò màá yò
A - O yà, wá ga lè yò
R - O yà, wá ga lè yò erù fè
A - A ga lè yò a ga lè yò a ga lè yò erù fè àga lè yò erù fè Òsanyìn
dé màá' rù ke fè
R - A ga lè yò a ga lè yò a ga lè yò erù fè àga lè yò erù fè Òsanyìn
dé màá' rù ke fè
A - Ori móko!
R - Bá mò kéré ké
A - Ori koko
R - Bá mò kéré ké
A - Èrò mi sè ò èrò
R - Èrò mi sèrò èrò èrò
A - Ire abá bá omo
R - Ire abá bá omo ire
A - Òsanyìn s'èkó sé re'kó
R - Sé re'kó sé re'kó s'èkó
A - Èlò wá' pè' kó sun arun
R - Èlò wá' pè' kó sun aro' su
A - Lànà' rukè lànà' rukè ewé òbe nf'ara bo
R - Lànà' rukè lànà' rukè ewé òbe nf'ara bo
A - Èkó fá èkó fá
R - Èkó fá èkó fá
A - Dé mã'ruke fè mã `rukè fè
R - Òsanyìn dé mã'ruke fè
A - Èlò wá pè kó l'arun dé
R - Èlò wá pè kó yára
A - Èlò wá pè kó sé' sé mi
R - Èlò wá pè kó yára
A - Òsanyìn nú àjé ki nú àjé ki baba ló odò kún
R - Òsanyìn nú àjé ki nú àjé ki baba ló odò kún
A - Òsanyìn rá wá àdé mi sé sé mi' re só só
R - Òsanyìn rá wá àdé mi sé sé mi' re só só
A - Eh! Olósanyìn má ku orò!
R - Òsanyìn Òsanyìn sí!
Djéjé ÒSANYÌN
A - Òsanyìn sá ru' wé, dà yí sá ru'wé, dà yí sá ru'wé, dà yí sá ru'wé
R - Òsanyìn sá ru' wé, dà yí sá ru'wé, dà yí sá ru'wé, dà yí sá ru'wé
A - Oti oti dé wá Òsanyìn rà oti dé wá
R - Oti oti dé wá Òsanyìn rà oti dé wá, oti oti dé wá
A - Òsanyìn se re bu wá Sàkpàtà ní se re bu wá o!
R - O yà o yà b'odù Òsanyìn se re bu wá
A - O yà o yà b'odù!
R - Òsanyìn se re bu wá
A - Òsanyìn èdè oogun làí-làí, èdè oogun làí-làí
R - Òsanyìn sá ru' wé èdè oogun làí-làí
A - So èle so èle!
R - Asejù rá nà re wá
A - So èle Òsanyìn ge
R - Asejù rá nà re wá
A - So so ìtan jèfá
R - Asejù rá nà re wá so ìtan jèfá, asejù rá nà re wá
Xapanã
Opanojé
Adabí
A - Jàró jàró Onídán koko o ní jàró
R - Jàró jàró Onídán koko o ní jàró
A - Mú jà mú jà, ké ri mú jà, mú jà mú jà, ké ri mú jà wò
R - Mú jà mú jà, ké ri mú jà, mú jà mú jà, ké ri mú jà wò
A - Mo be' lè fò jàró mo be' lè fò jàró
R - Mo be' lè fò jàró mo be' lè fò jàró
A - Àsà j'ewo ya fun wa wó a ba o erúnmalè
R - A sá jé nú yà fun wa wó a ba o erúnmalè
A - A ba o Erúnmalè
R - A ba o Erúnmalè
A - Okùn yé aiyé!
R - Ààyé yé ààyè
A - Èle mo be' lè fá tàlà bò lànà
R - A sá jé nú ba òní, òní oba o ya, a sá jé nú ba òní
A - Tàlà fò wá o! E lè fá tàlà fun malè
R - Tàlà fò wá o! E lè fá tàlà fun malè
A - Èké ba o, iná ba o, iná ba o, ebe l'isé ọdẹ
R - Èké ba o, iná ba o, iná ba o, ebe l'isé ọdẹ
A - Ààyè adé'lú a lùpa ju mule
R - Ààyè... adé'lú a lùpa ju mule
A - E lù e lùpa ju mule, e lù e lùpa ju mule wò
R - E lù e lùpa ju mule, e lù e lùpa ju mule wò
A - Oko ru mã oko ru mã afá bá mi ba orò
R - Aiyé aiyé oko ru mã oko ru mã afá bá mi ba orò
A - A ju ìjà sé lù sé lù
R - A ju ìjà kò lo kò lo
A - A ju ìjà kò lo kò lo
R - A ju ìjà sé lù sé lù
Opanijé
A - L'epo l'epo l'epo
R - Kó lè janjan kó lè'san
A - Níyà níyà níyà
R - Kó lè janjan kó lè'san
A - E mú jà, mú jà, mú jà k'otà
R - E mú jà, mú jà, mú jà k'otà
A - Jà kó pani, jà kó panígbe
R - Jà kó pa
A - Sònpònnó mo bè l'èrù òrìsà mo bè l'èrù
R - Ààyè èrù malè wó
A - Sàkpàtà ku'ta mi
R - Olomi l'awo
A - Sàkpàtà ku egba mo
R - Olomi l'awo
A - Sàkpàtà òbe ni tè õwo
R - Sàkpàtà òbe ni òbe ni tè õwo
A - E lè'gbára òní tè òbe l'awo, agbára oni tè òbe l'awo
R - E lè dáàdáá' gbára òní tè òbe l'awo
A - Àk'ara lókè lókè lókè
R - Àk'ara lókè lókè lókè àk'ara
A - Sàkpàtà só bo wè onà ìsó a ní só bò
R - Sàkpàtà só bo wè onà ìsó a ni só bò
A - Só bo wè Sàkpàtà mi l'arun yé só bo ibè ná súré mã Sàkpàtà má bé
sà wè
R - Só bo wè Sàkpàtà mi dá sun sé só bo ire ná sure ba Sònpònnó ààyè
ààyè
A - Mó sé ké'bà, mó sé ké'bà amodi so, yé ààyè! E lù ga mã mó sé ké'bà
amodi so,
yé ààyè! E lù ga mã mó sé ké'bà amodi so,
yé ààyè! E lù ga mã mó sé ké'bà amodi so, E odara !
R - Mó sé ké' bà, mó sé ké'bà amodi so, yé ààyè! sé ké'bà, mó sé ké'bà
amodi so, yé ààyè! Mó sé ké'bà, mó sé ké'bà amodi so, yé ààyè! Mó sé
ké'bà, mó sé ké'bà amodi so, E lè wá ra!
A - Ara mó ké lè mã jó, ara mó ké lè mã jó, mó ké lè mã, mó ké lè mã,
òbe
w'ara mó ké lè mã jó
R - Ara mó ké lè mã jó, ara mó ké lè mã jó, mó ké lè mã, mó ké lè mã,
òbe
w'ara mó ké lè mã jó
A - Sàkpàtà bá r'arun dé Sàkpàtà ra wè òní dé, Sàkpàtà bá r'arun dé
,Sàkpàtà ra wè òní dé wò
R - Bá' ra sé rà kún dé sà sà ru wè o ni pè wò, bá' ra sé rà kún dé sà
sà
,ru wè o ni pè wò
A - Sàkpàtà oníre kú a ju' re Sàkpàtà oníre kú a ju' re Sàkpàtà oníre
kó
lè' san Sàkpàtà oníre bè'lú' san
R - Sàkpàtà oníre kú a ju' re Sàkpàtà oníre kú a ju' re Sàkpàtà oníre
kó
lè' san Sàkpàtà oníre bè'lú' san
A - Bá' ra bá' ra mi' sorò Sàkpàtà bá' ra mi' sorò Sàkpàtà lóke lè mã
bá'
ra mi' sòro
R - Bá' ra bá' ra mi' sorò Sàkpàtà bá' ra mi' sorò Sàkpàtà lóke lè mã
bá'
ra mi' sòro
A - Le' bà mbò mã' ra ká já mã' ra ká já fi òla e wò
R - Le' bà mbò mã' ra ká já mã' ra ká já fi òla e wò
A - Ori móko dé là ibà bá l'èkó
R - Ibà mbò dé là ibà bá l'èkó
A - L'epo l'epo l'epo
R - K'ara mbò kara mbò
A - Bè'lú jà bè'lú jó olóníyà
R - Bè'lú jà bè'lú jó olóníyà
A - Kári re ma l'epo kún jà re ma kári re ma l'epo kún jà re ma
R - Wélé wá o yàn yè kári re ma l'epo kún jà re ma kári re ma l'epo
kún jà re ma
A - Ààyè ààyè Sònpònnó là nú ké rè Sònpònnó là nú ké rè là nú ké rè
ààyè ààyè
R - Ààyè ààyè Sònpònnó là nú ké rè Sònpònnó là nú ké rè là nú ké rè
ààyè ààyè
A - Èké rè ké má ìtan
R - Èké rè ké má ìtan
A - Alápa dé!
R - Ainon ribà ainon risé
Djéjé XAPANÃ
A - Ga mã jà sékó súnmó bé'run omo r'erò
R - Ga mã jà sékó súnmó bé'run omo r'erò
A - Ga mã ru sun bè wò bè wò
R - Ga mã ru sun bè wò bè wò
A - Ké mó maa sé lò' sé bè' lú jà
R - Akòja ebo ma sé lò' sé bè' lú jà
A - gò gò gò se mi wa gò gò gò s'ara wè
R - Àna rá wè éèdì oogun lai-lai
A - So so so Sàkpàtà omi so so so Sàkpàtà
R - Àna rá wè éèdì oogun lai-lai
A - Só bò mi' rókò
R - Ààyè ààyè Sàkpàtà
A - Á mã d'isé Sàkpàtà nísé wáiyé
R - Sàkpàtà nísé wáiyé, Sàkpàtà nísé wáiyé
A - Sogbó e! Sogbó e! A morí só a yé a morí só Sàkpàtà wá morí só
R - Sogbó e! Sogbó e! A morí só a yé a morí só Sàkpàtà wá morí só
A - Ga má se go, ga má lù' pepe, ga má lù' pepe, Sàkpàtà ga má se go
R - Ga má se go, ga má lù' pepe, ga má lù' pepe, Sàkpàtà ga má se go
A - Là nú' pepe àga njeun' bo
R - Ga mã là nú' pepe, là nú' pepe àga njeun' bo, ga mã là nú' pepe
A - Á mã sá pa yà, á mã sá pa yà, á mã sá pa yà dó e! Sàkpàtà ire, á
mã sá pa yà, á mã sá pa yà dó e!
R - Á mã sá pa yà, á mã sá pa yà, á mã sá pa yà dó e! Sàkpàtà ire, á
mã sá pa yà, á mã sá pa yà dó e!
A - E le má sá pa'yò
R - E le má k'elema
A - Bá yá ké bá yayò
R - Bá yá ké bá yayò
A - Ga mã jà yò jà yò, ga mã jà yò jà yò Sàkpàtà kú'ta mi
R - Ga mã jà yò jà yò, ga mã jà yò jà yò
A - A ba ikò
R - Páàpáà!
A - A ba ikò
R - A mã s'èpè
A - A lù pò!
R - Páàpáà!
ÌBEJÌ
Nagô
A - Dì owo dì owo tàlà d'Ìbejì èjì owo tàlà d' Ìbejì èjì owo olórun dé
o!
R - Dì owo dì owo tàlà d'Ìbejì èjì owo tàlà d' Ìbejì èjì owo olórun dé
o!
A - Dì owo dì owo ṣàngó d 'Ìbejì èjì owo tàlà d' ìbejì eji owo
R - Dì owo dì owo ṣàngó d 'Ìbejì èjì owo tàlà d' ìbejì eji owo
A - Elékùn jà ré o!
R - Ekùn jà ré ogun lò!
A - Owo owo èbùn l'èrùn dé dì lókè lo wá jà ajá okun dé elékùn jà ré o!
R - Okun jà ré ogun lo
A - Bàbá 'rúnmalè Olú fà
R - Bàbá 'rúnmalè Olú fà
A - Tàlà d'ibeji jó ṣàngó tàlà d'ibeji jó l'àlà ré wa
R - Anípé èjì jó
A - L'àlà ré wa
R - Anípé èjì jó
Aguere t'Oyá
A - Tàlà d'ibeji èjì w'owo tàlà d'ibeji èjì w'owo
R - ọya sé sùn 'malè tàlà d'ìbejì èjì w'owo
Nagô
A - Hù bádé hù bádé hù bádé a k'orò
R - Dada sélè hù bádé a k'orò
A - A sé sùn Sàkpàtà, yé sùn lábà wè
R - A sé sùn Sàkpàtà, yé sùn lábà wè
A - Esun lábà wè esun lábà wè
R - A sé sùn Sàkpàtà, yé sùn lábà wè
A - Àlà wí àlà wí erù rè bàbá
R - Àlà wí àlà wí e ù rè bàbá
A - Orò kun dé o!
R - Ara dé kun dé kun dé ká
ADÚRÀ-ORIN ÒSUN
Ijesá
A - Tàlà dé omi o tàlà yèyé màràjó
R - Òsun tàlà dé
A - Omi tàlà dé omi tàlà dé rì lànà
R - Òsun tàlà dé
A - Òsun tàlà dé omi o tàlà yèyé mi o!
R - Òsun tàlà dé
A - Ìyá' dò jí yèyé mi bàbà dé o ru kí lànà
R - Òsun tàlà dé
A - Eléwà ti Oba
R - Òsun àlà re wá
A - Yé bámi Òsun bi olomi, yé bámi Òsun bi olomi, yèyé pòndá e' lú nfá
ta ga rè lá yé bámi Òsun bi olomi
R - Yé bámi Òsun bi olomi, yé bámi Òsun bi olomi, yèyé pòndá e' lú nfá
ta ga rè lá yé bámi Òsun bi olomi
A - O yèyé Òsun pe rere mã
R - O yèyé Òsun pe rere mã
A - O yèyé o eléwà ti Òsun eléwà ti Òsun' Pòndá
R - O yèyé o eléwà ti Òsun eléwà ti Òsun' Pòndá
A - Omo d'Òsun o!
R - Eléwà ti Oba
A - Aláse kún o!
R - Eléwà ti Oba
A - Ogun pe ní' léwà
R - Omi ní wá rá wàrawàra omi ní wá rá
A - Òsun ìpòndá pàra wè lé wò
R - Òsun ìpòndá pàra wè lé wò
A - Olomi l'Òsun
R - Ato'níre olomi l'Òsun ato'níre
A - A mã' dúpè' lè oogun fà' yin
R - Òsun pe rere, Òsun pe rere
A - Aiyo yé yo!
R - Welewele wè lé Òsun wolé wè
A - Éèdì bá mbo' lé yò nú pe mi o!
R - Éèdì bá mbo' lé yò nú pe wa o!
A - Àgbere àgbè ké abe lè Òsun
R - Àgbere àgbè ké abe lè Òsun
A - O yèyé o ké mi ní ná o yé rò, ké mi ní ná yé rò
R - O yèyé o ké mi ní ná o yé rò, ké mi ní ná yé rò
A - Òsun pe mi o!
R - ọya d'oko erúnmalè o!
A - Omo kári rè wò
R - Kári rè kári rè mã kári rè mã
A - Asíri mímó'dù dé
R - E wá ṣiré ọya
A - Elegbé ti òsán
R - Yèyé m'orò
A - Aso t'omi yèyé mi pòn awò
R - Èrùn elè wá a jó Òsun èrùn ele
A - Yèyé k'omo k'omo ṣiré lò
R - Bàbà yín orò Òrìsà o yèyé o bàbà yín orò
A - Póndá lo sí mi
R - Omi ní lábà bájà yí
A - Póndá lo sí mi bè hù
R - Omi ní nà là sànbo omi ní nà
A - Kéké Òsun omi só rorò
R - Kèké kéké Òsun omi só rorò kéké
A - Òsun má ge tì omi má ní' lú
R - Tàlà dé yèyé e lù Òsun má ge tì
A - Epereké hùmò hùmò epere sé' rúnmalè o
R - Epe e ké hùmò hùmò epere sé' rúnmalè o
A - A mã wá Òsun yèyé ipè rè mã l'òrun
R - A mã wá Òsun yèyé ipè rè mã l'òrun
A - Ipè rè mã l'òrun, a dé lúwe yèyé o!
R - A mã wá Òsun yèyé ipè rè mã l'òrun
A - Òsun là mi o yèyé Òsun là ma'dù kèké Òsun là ma' dù kèké o Òsun là
mi o yèyé
R - Òsun là mi o yèyé Òsun là ma'dù kèké Òsun là ma' dù kèké o Òsun là
mi o yèyé
A - Èdé mú ká, èdé mú ká
R - Èdé mú ká yè ayé
A - Èlò ire olodò ga njó ire ká wè lé
R - Èlò ire olodò ga njó ire ká wè lé
A - Pòndá mi rere pòndá mi `re bàbà yí s'orò
R - - Pòndá mi rere pòndá mi `re bàbà yí s'orò
A - Ìyá mã b'okun pe rere ìyá mã b'okun pe rere
R - Ajojó ayé ìyá mã b'okun pe rere
A - Pòndá ire mo dìde pòndá ire mo júbà pòndá ire mo dìde òrìsà d'oko
R - Pòndá ire mo dìde pòndá ire mo júbà pòndá ire mo dìde òrìsà d'oko
A - Èlò ire mo júbà
R - Òrìsà d'oko
A - Ire adé owó ire adé wá omi ni nà bá, adé owó ire adé wá
R - Ire adé owó ire adé wá omi ni nà bá, adé owó ire adé wá
A - Àké mi sé' lédè wó wó o yèyé afi òrò afá ki lò fá mã ki b'ohun
R - Àké mi sé' lédè wó wó o yèyé afi òrò afá ki lò fá mã ki b'ohun
A - Adé wòran adé wòran adé wòran yè o sé' lé bàbà ikò fi odara a bá
ikò yèyé
R - Adé wòran adé wòran adé wòran yè o sé' lé bàbà ikò fi odara a bá
ikò yèyé
A - A bá ikò a bá ikò yèyé a ba láàrin t'onà bò a ba ikò yèyé
R - A bá ikò a bá ikò yèyé a ba láàrin t'onà bò a ba ikò yèyé
A - A bá láàrin t'onà bò
R - A ba ikò yèyé
A - A mò rorò okun orò éèdì Òsun l'oba
R - A mò rorò okun orò éèdì Òsun l'oba
A - Bàbà mi s'orò
R - A wò'rò a wò'rò
A - Bá rà bá ru ekùn faiya bá rà bá ru èlè o
R - Bá rà bá ru ekùn faiya bá rà bá ru èlè o
A - Bá rà ohun bá rá ọdẹ emí r'emí d'oko
R - Bá rà ohun bá rá ọdẹ emí r'emí d'oko
A - E ire e ire pòndá o!
R - Yé! èlò má ilo
A - Èlò iru
R - Ge nge nge
A - Omi d'oko o' yánlà mã ti kí bérè
R - Omi d'oko o' yánlà mã ti kí bérè
A - Ki bàbà mã ki tò loní
R - O yèyé ebora ebora
A - Èlò ìrò dé
R - A d'oko bàbà yí s'òrò èro
A - O Yemoja o Yemoja mã bokun bàbà yí s'òrò
R - O Yemoja o Yemoja mã bokun bàbà yí s'òrò
A - Dé mù
R - Bàbà yí s'òrò
A - Pòndá
R - Bàbà yí s'òrò
A - D'oko
R - Bàbà yí s'òrò
A - `Mo kéré omo délé
R - Ara' mo kéré' mo délé
A - Yèyé kári o, yèyé kári o
R - Ara dé Òsun kári o kári o
A - Yèyé' bè sàn lè wò bomore yèyé' bè sàn lè wò bomore
R - Òsun dé olónà yèyé bè sàn lè wò bomore
A - Òsun dé mù o
R - E wá ṣiré ọya
A - Òsun pòndá ki rawó
R - E wá ṣiré ọya
A - Orò kún má ì lo
R - Wá aso Òsun !
A - Orò kún má rì'lé
R - Wá aso Òsun !
A - Òkêré rebo
R - Òkêré rebo!
A - O fé níse
R - O fé níse ebo
A - Yèyé bá ki re ma yèyé d'oko lodò
R - Yèyé yèyé yèyé d'oko lodò
Djéjé ÒSUN
A - Iyãfin o dé s'àpáta afin á mã ọdẹ sí mã
R - Iyãfin o dé s'àpáta afin á mã ọdẹ sí mã, iyãfin o dé
A - Pòndá sun wá mi
R - L'àlà rèé wá l'arùn wè
A - Jagun á jà' rùn dé, jagun á jà' rùn dé, jagun á jà' rùn dé o!
R - Jagun á jà' rùn dé, jagun á jà' rùn dé, jagun á jà' rùn dé o!
A - D'àle d'àle tàp'ègún
R - D'àle d'àle
YemOnjá
Huntó
A - Yemoja sélè olodò bàbà òròmi o Yemoja elemí jà'lé o bàbà òròmi o
R - Yemoja sélè olodò bàbà òrò mi o Yemoja elemí jà'lé o bàbà òròmi o
A - Yemoja pàse ki pàse sùn, a Yemoja sé sùn, òrun awo a Yemoja sá èbá
a Osun' dúpé wò bàbà òròmi o
R - Yemoja pàseki pàse sùn, a Yemoja sé sùn, òrun awo a Yemoja sá èbá
a Osun' dúpé wò bàbà òròmi o
A - Adósù mò gbé' ke ara orò adósù mò gbé' ke ara sé sùn
R - Yemoja kún ara kún ara orò o yà'dósù mò gbé dé ara orò
A - A fun lélè àsikò á mã là ire o
R - Èwó awo a bè wò e ún á má rà isó èwó awo a bèbè wò
A - Elemí Òsun ìyá'gbára níire o!
R - Èwó awo a bè wò e ún á má rà isó èwó awo a bèbè wò
A - A dé èkó a bè l'èwó
R - èwó awo a bèbè wò
A - Orúnmilà oketsé oketsé o yà a ga jú Òsun là oketsé oketsé o yà
Òsun eléwé le
R - A ká òrò oketsé oketsé erò a ga jú Òsun là oketsé oketsé erò o yà
eléwé le
A - Okè rè wa sé sùn o!
R - Okè rè òrìsà
A - Okè rè ìyá jà bá o!
R - Okè rè òrìsà
Adabí
A - Yemoja Ògún ofo rí lá bá'tà yá omi fò rí l'Awo
R - Yemoja Ògún ofo rí lá bá'tà yá omi fò rí l'Awo
A - Yemoja, Ògún
R - Awo' rò
A - Yemoja Bomi
R - Awo' rò
A - Yemoja t'omi t'omi t'omi o
R - Á t'omi rè emí rè mi
A - O yà ọdẹ là bàbá èlè Yemoja Ògún là bàbá èlè
R - O yà ọdẹ là bàbá èlè Yemoja Ògún là bàbá èlè
A - Yemoja e là o!
R - Yemoja' kè bá'tà bá'tà bàbá èlè
Huntó
A - `Kè tu Nèné' kè tu Nèné, Yemoja e là okè bá ọdẹ
R - `Kè tu Nèné kè tu Nèné, Yemoja e là okè bá ọdẹ
A - Tò tò tò o yà béè i' kè o yà béè i o yà béèni' kè
R - Tò tò tò o yà béèni' kè o yà béèni o yà béè i' kè
A - Orò kún má ri'lé, orò kún má í lo
R - Yemoja sélè Olódò
A - Yemoja má ri'lé, Yemoja má í lo
R - Yemoja sélè Olódò
A - Odò kún má ilé, Odò kún má í lo
R - Yemoja sélè Olódò
A - Omo fìre èrè' dé o!, omo fìré èrè' dé o, onà kún' bè o
R - Omo fìre èrè' dé o
A - Onà kún' bè o
R - Omo fìre èrè' dé o
Djéjé YEMONJÁ
A - Aná'ré wá, aná' ré wá yèwo
R - Aná'ré wá, aná' ré wá yé
A - Yè Yemoja aná' ré wa yèwo
R - Aná'ré wá, aná' ré wá yé
A - Etu mã là didé, etu mã là didé, nlo burúkú o kó' sù nlá, etu mã là
didé
R - Etu mã là didé, etu mã là didé, nlo burúkú o kó' sù nlá, etu mã là
didé
A - O yà bá dilé o yà bá dilé, nlo burúkú o kó sù nlá, o yá bá dilé
R - O yà bá dilé o yà bá dilé, nlo burúkú o kó sù nlá, o yá bá dilé
A - Òní òpé õsà ire mã!
R - Ebo òní òpé õsà ire mã ebo
A - Bàrà odì, odì odì odì Bàrà
R - Bàrà odì, odì odì òdí Bàrà
A - Ògún bá rà' ké bá rà' ké bá rà bá yayò
R - Ògún bá rà' ké bá rà' ké bá rà bá yayò
A - Èmí r'emi re k'èwé nlo burúkú rè k'ewé
R - Èmí r'emi re k'èwé nlo burúkú rè k'ewé
A - Á mã kère ère w'e è
R - Lànà rè wá
ÒSÁLÁ
Ijesá
A - E jí yá wá wá o! Bàbá ìsòrò
R - E jí wáiyé Bàbá'rúnmalè e jí wá
A - Elú' wà pè kó o Bàbá
R - Elú' wà pè kó Erúnmalè
A - Elú' wà pè kó omo jà
R - Elú wà pè kó Erúnmalè
A - Ayo l'omi l'àwa' nà réè wò! Kó rí foribalè
R - Olomi' nà o Aladé k'ori foribalè
A - Ayo fi òla ayo fi òla Yèyé bàbà' runmalé
R - Ayo fi òla ayo fi òla Yèyé bàbà' runmalé
A - Á mã k'èrè k'èrè k'èrè, wá mã k'èrè dé òrìsà
R - Á mã k'èrè k'èrè k'èrè, wá mã k'èrè dé òrìsà
A - Omi ni'nà bá tìyà omi ni'nà bá lókun
R - Omi ni'nà bá tìyà omi ni'nà bá lókun
A - Wolé wolé wolé omi á tu Bàbá ìsòrò
R - Wolé wolé wolé omi á tu Bàbá ìsòrò
A - Wolé wá o ! Wolé dé bàbá o!
R - Wolé wá o ! Wolé dé bàbá o!
A - E bàbá lokè fun mi bòkun
R - Òkêrè ké le bò má yà ayo òkêrè ké le bò má yà
A - E mã wá e pe' rúnmalè odò
R - Erò e mã wá e pe' rúnmalè odò erò
A - Àlà mókèé mókèé sé
R - Àlà o o o! bàbá
A - Òòsà-nlà dé òròmi là ìyà bàbà yi sòro òròmi là ìyà
R - Òòsà-nlà dé òròmi là ìyà bàbà yi sòro òròmi là ìyà
A - Òòsà-nlà dé òròmi là ìyà, òròmi là ìyà yi sòro
R - Òòsà-nlà dé òròmi là ìyà, òròmi là ìyà yi sòro
A - Eiye iye o! í yé òròmi là ìyà
R - Eiye iye o! í yé òròmi là ìyà
A - Bé l'èrù bé l'erù bé l'èrùn Òrìsà-nlá malè odò
R - Bé l'èrù bé l'erù bé l'èrùn Òrìsà-nlá malè odò
Igbin
A - Aláfìn olá yè dé bàbá're wá
R - Aláfìn olá yè dé bàbá're wá
A - Òòsà-nlà bé l'èrù
R - Epe e mã f'ara
A - Má kosè Òòsà-nlà má kosè bàbá igbó má kosè
R - Bàbá igbó má kosè Òòsà-nlà má kosè bàbá igbó má kosè
A - Sá padà o ṣiré!
R - F'ara b'odò
A - E kí' lú wá pés'orò í là o, e kí' lú wá pés'orò í là o, bàbá o sí
mã, ìyá là o sí mã, e kí' lú wá pés'orò í là o
R - E kí' lú wá pés'orò í là o, e kí' lú wá pés'orò í là o, bàbá o sí
mã, ìyá là o sí mã, e kí' lú wá pés'orò í là o
A - O kí kí Obì õfà rí re wò, o kí kí Obì õfà rí re, Obì õfà òrun, Obì
õfà Òsun o kí kí Obì õfà rí re wò
R - O kí kí Obì õfà rí re wò, o kí kí Obì õfà rí re, Obì õfà òrun, Obì
õfà Òsun o kí kí Obì õfà rí re wò
A - Yèwo o yèwo! Awo Òòsà-nlà Òrúnmilà í là o
R - Yèwo o yèwo! Awo yèwo dé Orúnmilà yá
A - Olú pepe o! airà bàbà já nire olúfá í rà
R - Olú pepe o! airà bàbà já nire olúfá í rà
A - Kó l'imò kó l'imò kún
R - F'ara rá ìjó kó l'imò kún f'ara rá yí
A - Yèyé èpa bi yàn, yèyé èpa bi yàn, á má sé lo òní b'òkun má korò,
yèyé èpà bi yàn á má sé lo òní b'òkun má korò
R - Yèyé èpa bi yàn, yèyé èpa bi yàn, á má sé lo òní b'òkun má korò,
yèyé èpà bi yàn á má sé lo òní b'òkun má korò
A - Á bá là Ijùgbè, á bá là Ijùgbè, á má sé lo òní b'òkun má korò, á
bá là Ijùgbè, á má sé lo òní b'òkun má korò
R - Á bá là Ijùgbè, á bá là Ijùgbè, á má sé lo òní b'òkun má korò, á
bá là Ijùgbè, á má sé lo òní b'òkun má korò
A - Onà jé o adúpe re o!
R - Onà jé o adúpe re o!
A - Babá sé ké tún l'erè uma là
R - Babá sé ké tún l'erè uma là
A - Ìlekè' lekè d'omi o!
R - Bàbá òrìsà d'omi o!
A - Òrìsà tàlà asó'mi re o odòlómi ná wè odòlómi ná wè Òrìsà tàlà
asó'mi re o
R - Òrìsà tàlà asó'mi re o odòlómi ná wè odòlómi ná wè Òrìsà tàlà
asó'mi re o
A - Olórun e jí hù pe a ba'lú ri olórò
R - Olórun e jí hù pe a ba'lú ri olórò
A - O yà o álá
R - Òkè sé okè sé
A - Yé ebi ebi á jeun o elébi ebi á jeun o oní bàbá elépe o á mi mõre
mi jà kún dá o oní bá bí f'oba elépe o
R - Yé ebi ebi á jeun o elébi ebi á jeun o oní bàbá elépe o á mi mõre
mi jà kún dá o oní bá bí f'oba elépe o
A - Òrìsà mi mõre mi jà kún dá o
R - E le Bàbá elépe o
A - O lélè mbá rà o lélè mbá rà ó Olófin á Òrìsà-nlà Olófin á o Bàbá
R - O lélè mbá rà o lélè mbá rà ó Olófin á Òrìsà-nlà Olófin á o Bàbá
A - E le kiákiá kún fè rere
R - Babalásè ké a jù pe òrò
A - Òrisà-nlà lé'rùn, Òòsà-nlà lé'rùn olófín á Òrìsà-nlà olófín o bàbá
R - Òrisà-nlà lé'rùn, Òòsà-nlà lé'rùn olófín á Òrìsà-nlà olófín o bàbá
A - E bò Òrisà-nlà Òrìsà-nlà e bò Òòsà-nlà Òrìsà-nlà ebi t'ánà bò e bò
Òrisà-nlà Òrìsà-nlà
R - E bò Òòsà-nlà Òrìsà-nlà e bò Òòsà-nlà Òrìsà-nlà ebi t'ánà bò e bò
Òrisà-nlà Òrìsà-nlà
A - E bò olófin á Òrìsà-nlà
R - E bò olófin á Òrìsà-nlà
A - Oní mó' kùn sé rà oní mõkún sé rà
R - Bàbá igbó oní mõkún sé rà
A - Oní mõkún ṣiré
R - Bàbá l'ijà
A - Ò òrisà-nlà kó mi yà asó bàbá yí kékè, Òòsà-nlà kó mi yà asó olú
rere
R - Ò òrisà-nlà kó mi yà asó bàbá yí kékè, Òòsà-nlà kó mi yà asó olú
rere
A - Bàbá sé' kè tu l'erò oní mõkún dú l'erò bàbá bàbá sé kè tu l'erò
elú lélè là ìpò
R - Bàbá sé kè tu l'erò Bàbá sé kè tu l'erò bàbá bàbá sé kè tu l'erò
lélè e lélè o!
A - Lé'po!
R - L'erò' lé lélè o
A - Lókè bò mi nà
R - Bájà yí
Djéjé ÒSÁLÁ
A - Òrìsà wè i b'okun
R - Bàbá Òrìsà wè i b'okun lo
A - Mo balè mo balè!
R - Wí ni wí ni mo balè!
A - Otà wè `tà wè `tà wè dé bàbá `tà wè
R - Otà wè `tà wè `tà wè dé bàbá `tà wè
A - Tò'lú mbe tàlà' lú'fá yìn, tò'lú mbe tàlà' lú'fá o!
R - Tò'lú mbe tàlà' lú'fá yìn, tò'lú mbe tàlà' lú'fá o!
A - E Kalè kalè kale jó!
R - E rè'ré rè kale jó! MO PÍN ÒRÒ MI
A - Oní mo níwà sun pín wá sun pín òrò
R - Oní mo níwà sun pín wá sun pín òrò
Publicar un comentario